James Manager |
---|
|
Alága ẹ̀ka People's Democratic Party ti ìpị́nlẹ̀ Delta |
---|
In office ọdún 1998 – ọdún 1999 |
Arọ́pò | Pius Sinebe |
---|
Aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga ọdún 2007 |
Constituency | Gúúsù Delta |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | Oṣù Keje 1960 (ọmọ ọdún 64) |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
---|
Profession | Olóṣèlú |
---|
James Manager jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Delta ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2003 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí