Sen Adamu Gumba |
---|
|
Aṣojú Gúúsù Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kẹjọ Ọdún 23 2010 |
Asíwájú | Bala Mohammed |
---|
Arọ́pò | Sen Ali Wakili |
---|
Constituency | Gúúsù Bauchi |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kẹ̀wá 1948 (1948-10-10) (ọmọ ọdún 76) |
---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
---|
Profession | Olóṣèlú |
---|
Adamu Gumba jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Ó jẹ́ olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti Bauchi.[2]
Àwọn ìtọ́kasí