Emmanuel Paulker |
---|
|
Aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga Ọjọ́ Ọ̀kàndínlógún Oṣù karún Ọdún 2007 |
Asíwájú | David Brigidi |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹ̀wá 1955 (1955-10-15) (ọmọ ọdún 69) Ìpínlẹ̀ Bayelsa |
---|
Emmanuel Paulker (bíi ní Ọjọ́ karùndínlógún Oṣù kẹwá Ọdún 1955) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí