David Cobbina Brigidi |
---|
|
Aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà |
---|
In office Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2007 |
Arọ́pò | Emmanuel Paulker |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Bayelsa |
---|
David Cobbina Brigidi jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 1999 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí