Omar Abubakar Hambagda |
---|
|
Aṣojú Gúúsù Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà |
---|
In office Oṣù karún ọdún 2003 – Oṣù karún ọdún 2011 |
Asíwájú | Abubakar Mahdi |
---|
Arọ́pò | Mohammed Ali Ndume |
---|
Constituency | Gúúsù Borno |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Keje 1949 (1949-07-28) (ọmọ ọdún 75) |
---|
Aláìsí | Oṣù karún ọdún 2016 |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Nigeria Peoples Party (ANPP) |
---|
Profession | Onímọ̀ ẹ̀kọ́ àti olóṣèlú |
---|
Omar Hambagda jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọdún 2003 sí 2011. Wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Borno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà lábẹ́ òṣèlú All Nigeria Peoples Party (ANPP) ní ọdún 2003.[1]
Wọ́n tun yàn ní ọdún 2007, tí ó sì di ipò yìí mú di ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party, PDP.[2][3][4]
Àwọn ìtọ́kasí