Annie OkonkwoAnnie Okonkwo je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2007 doni.
Clement Annie Okonkwo (ti a bí ni ojó ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960) ọ dibo ile asofin fun agbegbe aarin Anambra Anambra State, Nigeria, iṣẹ beere ni ojó kokandinlogbon osu karún ọdún 2007. Ọkàn lára ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party (PDP).[1] Okonkwo ẹni tí a bí ni ojo ketalelogun oṣù kàrún ọdún 1960 ní Ojoto, l'ẹba Onitsha ni Anambra State.[2] O ka ìwé síwájú sí láti gbà diploma nínú ìsàkóso, Harvard University, USA (1997-1998), ìwé síwájú Diploma nínú oníṣòwò ofin ati ìwà, University of Lagos (1995-1997) pẹlu diploma síwájú sí nínú ìpolówó ọjà, University of Lagos (1994 - 1995).[1] Nínú ìṣòwò, o kò ilé iṣẹ nla ti ọ gbà egberun méje ènìyàn ní àwọn ilé iṣẹ Reliance Telecomm, Clemco Industries, Modern Communications (satellite TV Network), MacClemm Marketing Communications, Sunflower Nigeria and Pentagon Oil.[2] Lẹyìn tí ọ gbà àga gẹgẹ bí olóṣèlú, a Yàn láti sójú ìgbìmò lori Upstream Petroleum Resources, ọrọ awọn ọlọpa, agbegbe (vice-chairman) ati ọgbin.[1] Nínú ayẹwo iṣẹ awọn olóṣèlú ni oṣù kàrún ọdún 2009, ThisDay se àpèjúwe okonkwo gẹgẹ bí ẹni tí ọ fi múlẹ láti jẹ kí ohun ọgbin àti oúnjẹ din owó fún ará ìlú àti awọn ara òke òkun ile Naijiria le ri ra .[3] Ni oṣù Kejì ọdún 2010 o di je Anambra State bí gomina.[4] sibẹsibẹ, o pa danu sí ọwọ gomina ti a Yàn , Peter Obi,[5] Itokasi
Information related to Annie Okonkwo |