Nepal (Nepali: नेपाल Àdàkọ:IPA-ne), àlòṣiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nepal,[12] jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní Gúúsù Ásíà. Gbogbo rẹ̀ búdòó sí àwọn òkè Himalayas, sùgbọ́n ó tún ní àwọn apá Indo-Gangetic Plain. Nepal ni orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ 49k gẹ́gẹ́bí iye èniyàn àti orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ 93k gẹ́gẹ́bí agbègbè. Nepal jẹ́ orílẹ̀-èdè àrin-ilẹ̀, ó sì ní bodè mọ́ Ṣáínà ní àríwá àti mọ́ Índíà ní gúúsù, ìlàòrùn àti ìwọ̀òrùn, nígbàtí Bangladesh wà ní 27 km (17 mi) sí etí apágúúsùilàòrùn àti Bhutan jìnnà si látọ̀dò ìpúnlẹ̀ India Sikkim. Nepal has a diverse geography, including fertile plains, subalpine forested hills, and eight of the world's ten tallest mountains, including Mount Everest, the highest point on Earth. Kathmandu is the capital and the largest city. Nepal is a multiethnic country with Nepali as the official language.
- Nepal
-
Kathmandu
-
Swayambhunath
-
Patan
-
Bhaktapur
-
Himalaya
-
Himalaya
-
Kaski District
-
Mustang
-
Mustang
Awon itokasi