ISO 3166 je apa meta opagun amioro, fun agbegbe lati se amioro fun awon orile-ede, awon agbegbe to ba le won ati ipin apa won, ti Àgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págun tesiwejade. Oruko re gangan ni Awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won.
Awon apa
Itokasi