ISO 3166-2:GH ni akoole ninu ISO 3166-2, apa opagun ISO 3166 ti International Organization for Standardization (ISO) tejadesiwe to setumo awon amioro fun oruko awon ipinsabe koko fun orile-ede Ghana (ti amioro ISO 3166-1 alpha-2 re je GH).
Lowolowo awon agbegbe 10 ni amioro. Amioro kookan bere pelu GH- to je titele pelu leta meji:
Itokasi