Japan
|
---|
|
|
|
|
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Tokyo (de facto) |
---|
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | None[1] |
---|
Lílò regional languages | Aynu itak, Eastern Japanese, Western Japanese, Ryukyuan, and several other Japanese dialects |
---|
National language
National Scripts
| Japanese
Kanji Hiragana Katakana |
---|
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 98.5% Japanese, 0.5% Korean, 0.4% Chinese, 0.6% other[2] |
---|
Orúkọ aráàlú | Japanese |
---|
Ìjọba | Parliamentary democracy with constitutional monarchy |
---|
|
| Naruhito (徳仁) |
---|
| Fumio Kishida (岸田 文雄) |
---|
|
Aṣòfin | National Diet |
---|
| House of Councillors |
---|
| House of Representatives |
---|
Formation |
---|
|
| February 11, 660 BC[3] |
---|
| November 29, 1890 |
---|
| May 3, 1947 |
---|
| April 28, 1952 |
---|
|
Ìtóbi |
---|
• Total | 377,975 km2 (145,937 sq mi)[4] (61st) |
---|
• Omi (%) | 1.4 |
---|
Alábùgbé |
---|
• 2021 estimate | 125,600,000[5] (10th) |
---|
• 2020 census | 126,226,568[6] |
---|
• Ìdìmọ́ra | 334/km2 (865.1/sq mi) (24th) |
---|
GDP (PPP) | 2021 estimate |
---|
• Total | $5.586 trillion [7] (3rd) |
---|
• Per capita | $32,608[8] (23rd) |
---|
GDP (nominal) | 2021 estimate |
---|
• Total | $5.378 trillion[8] (3rd) |
---|
• Per capita | $44,928[8] (23rd) |
---|
Gini | 38.1 (2002)[9] Error: Invalid Gini value |
---|
HDI (2007) | ▲ 0.960[10] Error: Invalid HDI value · 10th |
---|
Owóníná | International Symbol ¥ Pronounced (Yen) Japanese Symbol 円 (or 圓 in Traditional Kanji) Pronounced (En) (JPY) |
---|
Ibi àkókò | UTC+9 (JST) |
---|
| not observed |
---|
Irú ọjọ́ọdún | yyyy-mm-dd yyyy年m月d日 Era yy年m月d日 (CE−1988) |
---|
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
---|
Àmì tẹlifóònù | 81 |
---|
ISO 3166 code | JP |
---|
Internet TLD | .jp |
---|
Japan (日本, Nihon or Nippon?, 日本国 Nippon-koku tabi Nihon-koku) jẹ́ orílẹ̀-èdè erékùṣù ní Ìlà Oòrùn Asia. Ó pàlà pẹ̀lú Òkun Pàsífíìkì, o wa ni ilaorun Okun Japan, Saina, Ariwa Korea, Guusu Korea ati Rosia, o gun lati Okun Okhotsk ni ariwa de Okun Ilaorun Saina ati Taiwan ni guusu. Awon leta ti won fi n ko oruko Japan tumo si "orisun orun", eyi lo je idie ti a fi n pe Japan ni "Ile Iladide Orun".
Japan jẹ́ arkipelago àwọn Erékùṣù 6,852.[11] àwọn erékùṣù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshū, Hokkaidō, Kyūshū àti Shikoku, ti àpapọ̀ wọ́n jẹ́ èdè mẹ́tàdínlọ́gọ́rùún (97%) ìtóbi ilẹ̀ Japan. Opo awon erekusu wonyi je oloke, opo je onileru; fun apere, ibi gigajulo ni Japan, Oke Fuji, je onileru. Japan je orile-ede ikewa to iye awon eniyajulo, pelu awon eniyan ti won to egbegberun 128. Agbegbe Titobiju Tokyo, to ni oluilu de facto Tokyo ati awon ibile ayika re, ni o je agbegbe metropoli titobijulo lagbaye pelu iye eniyan to to egbegberun 30.
Iwadi iseoroayeijoun fihan pe awon eniyan ti ungbe ni Japan lati igba to ya bi igba Okutaijoun Oke. Igba akoko ti a ko gbo nipa oruko Japan ninu iwe akoole je ninu awon iwe itan Saina lati orundun 1k SK. Ipa latodo awon orile-ede miran je titele pelu idagbe igba pipe bo se han gbangba ninu itan Japan. Ni igbeyin orundun 19k ati 20k ijabori ninu Ogun Saina ati Japan Akoko, Ogun Rosia Japan, ati Ogun Agbaye 1k gba Japan laye lati fe ile re nigba itoja ogun. Ogun Saina ati Japan Keji odun 1937 tan titi de Ogun Agbaye 2k, to wa sopin ni 1945 leyin ijubombu atomu si Hiroshima ati Nagasaki. Lati igba atunse ibagbepo re ni 1947, Japan ti di oba onibagbepo olokan pelu obaluaye atiileasofin aladiboyan tounje Diet mu.
Alagbara itokowo ninla,[12] Japan ni o ni itokowo keta totobijulo lagbaye gegebi GIO oloruko[13] ati gegebi ifiwe agbara iraja. Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati arajalatode kerin titobijulo lagbaye. Botilejepe Japan lonibise ti jowo eto re lati gbe ogun, o di ile-ise ologun odeoni mu fun abo ati ise alafia. Leyin Singapore, Japan lo ni ipaniyan to kerejulo lagbaye.[14] Gegebi UN ati WHO se diye, Japan lo ni ireti igbeaye gigunjulo larin gbogbo awon orile-ede lagbaye. Bakanna o tun ni iku omo-owo tokerejulo keta, gegebi UN se so.[15][16]
Itokasi