Brunei (pípè /bruːˈnaɪ/), fun onibise gege bi Orile-ede ile Brunei Darussalam tabi Orileabinibi ile Brunei, Ibi Alafia (Àdàkọ:Lang-ms, Jawi: بروني دارالسلام), je orile-ede to budo si eti odo ariwa erekusu ile Borneo, ni Guusuilaorun Asia. Oto si eto odo re pelu Okun Guusu Saina o je yiyipo patapata pelu ipinle Sarawak ni Malaysia, ooto si n pe o je pipinya si apa meji pelu Limbang, to je apa Sarawak.
Itokasi