Orúkọ
|
Image
|
Orírun
|
Traditional protein
|
Àpèjúwe àti àwọn ohun èlò
|
Ají de gallina
|
|
Peru
|
Àkùkọ adìẹ
|
Peruvian chicken stew
|
Alicot
|
|
France
|
Offal
|
Ọbẹ̀ tí a ṣe láti ara ẹran adìẹ giblets pàápàá orí, ẹsẹ̀, àti apá
|
Andrajos
|
|
Spain (Jaén)
|
Ẹran ìgbẹ́
|
Ọbẹ̀ tòmátò, àlùbọ́sà, garlic, ata rodo, àti ejoro
|
Asam pedas
|
|
Indonesia Malaysia
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ tí a fi ẹja àti àwọn ohun èlò mìíràn sè
|
Balbacua
|
|
Philippines
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ ẹran màálù
|
Bamia
|
|
Egypt
|
Ọmọ ẹran àgùntàn
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ilá àti ẹran àgùntàn[1][2]
|
Beef bourguignon
|
|
France (Burgundy)
|
Ẹran màálù
|
Burgundy]], pẹ̀lú àwọn ohun èlò mìíràn
|
Beef Stroganoff
|
|
Russia France
|
ẹran màálù
|
Beef Stroganoff tàbí beef Stroganov
|
Bicol express
|
|
Philippines
|
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tàbí màálù
|
Ọbẹ̀ tí a sè láti pẹ̀lú ata àti ẹran màálù tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀, mílíìkì, ẹja gbígbẹ, àlùbọ́sà, àti ata ilẹ̀.
|
Bigos
|
|
Poland Ukraine Lithuania
|
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
Ọbẹ̀ onírúurú ẹran àti àwọn ohun èlò ìsebẹ̀ mìíràn
|
Birnen, Bohnen und Speck
|
|
Germany
|
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
A máa ń sè é pẹ̀lú ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
Birria
|
|
Mexico
|
Ewúrẹ́
|
Ọbẹ̀ ẹran aláta tí a sè pẹ̀lú ẹran ẹlẹ́dẹ̀, ẹran ewúrẹ́, tàbí ẹran àgùntàn èyí tí wọ́n sáábà máa ń jẹ nígbà ìsinmi lẹ́nu iṣẹ́ bíi ọdún Kérésìmesì
|
Blanquette de veau
|
|
France
|
Veal
|
Bright veal ragout pẹ̀lú mirepoix
|
Blindhuhn
|
|
Germany (Westphalia)
|
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
Ọbẹ̀ àwọn Westphalian èyí tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹ̀wà, ẹ̀fọ́ àti bacon
|
Booyah
|
|
United States (Upper Midwest)
|
Various
|
Ọbẹ̀ tí ó kún fún onírúurú àwọn ẹran pẹ̀lú ẹ̀fọ́ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
|
Bosanski lonac
|
|
Bosnia and Herzegovina
|
Àgùntàn
|
Ọbẹ̀ àwọn Bosnian tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù, àgùntàn, kárọ́ọ̀tì, ànàmọ́, ata ilẹ̀ abbl
|
Bouillabaisse
|
|
France (Marseille)
|
Seafood
|
Ọbẹ̀ ẹja odò pẹ̀lú ẹ̀fọ́
|
Brongkos
|
|
Indonesia (Yogyakarta and Central Java)
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran màálù
|
Brodetto
|
|
Italy
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja, èyí tí ó yàtọ̀ láti ìletò kan sí èkejì
|
Brudet
|
|
Croatia Montenegro
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja èyí tí a máa ń jẹ pẹ̀lú polenta, tí ó fi ara jọ brodetto àwọn Italian
|
Brunswick stew
|
|
United States (South)
|
Ẹran ìgbé
|
Ọbẹ̀ tí a fi tòmátò se, tí ó kún fún ẹ̀wà, àgbàdo, ilá, àti àwọn ẹ̀fọ́, bẹ́ẹ̀ ni a tún le lo àwọn ẹran bíi: Ọ̀kẹ́rẹ́ tàbí Ehoro, ṣùgbọ́n ẹran adìẹ, ẹlẹ́dẹ̀, àti ẹran màálù jẹ́ èyí tí a le lò pẹ̀lú.
|
Trippa alla milanese (Buseca in South America)
|
Trippa alla milanese.JPG
|
Italy Argentina Uruguay
|
Offal
|
Ọbẹ̀ àwọn Italian èyí tí a tún lè rí ní Uruguay àti Argentina, ó fi ara pẹ́ callos ti àwọn Spanish
|
Buddha Jumps Over the Wall
|
|
China
|
Ẹja
|
Cantonese variation on shark fin soup
|
Buğu kebabı
|
|
Turkey
|
Ọmọ ẹran àgùntàn
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ọmọ ẹran àgùntàn àti ẹ̀fọ́ nínú oúnjẹ àwọn Turkish
|
Burgoo
|
|
United States (Midwest and South)
|
Ẹran ìgbẹ́
|
Ọbẹ̀ tí fi onírúurú ẹran ìgbẹ́ sè
|
Cabbage stew
|
|
Central Europe
|
Vegetarian
|
A máa ń sè é pẹ̀lú cabbage
|
Cacciatore
|
|
Italy
|
Adìẹ
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran ṣíkìn, ata, àti àlùbọ́sà
|
Cacciucco
|
|
Italy
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja tí a fi onírúurú ẹja sè pẹ̀lú ata
|
Cachupa
|
|
Cape Verde
|
Ẹran ewúrẹ́
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àgbàdo, ẹ̀wà, ẹja, tàbí ẹran màálù, ewúrẹ́, tàbí ti ṣíkìn.
|
Caldeirada
|
|
Portugal
|
Seafood
|
Ọbẹ̀ tí a sè tí ó kún fún onírúurú àwọn ẹja, àti ànàmọ́, pẹ̀lú tòmátò àti àlùbọ́sà.
|
Caldereta de cordero
|
|
Spain
|
Àgùntàn
|
Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn
|
Caldo avá
|
|
Paraguay
|
Offal
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ìfun ẹran pẹ̀lú àwọn tinú ẹran
|
Caldo gallego
|
|
Spain
|
Ẹran ewúrẹ́
|
Ọbẹ̀ ẹran ewúrẹ́
|
Callaloo
|
|
Caribbean West Africa
|
Vegetarian
|
Oúnjẹ àwọn Caribbean
|
Callos
|
|
Spain
|
Offal
|
Ọbẹ̀ tí ó gbajúmọ̀ ní Spain, wọ́n kà á gẹ́gẹ́ bíi oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn ará Madrid,níbi tí wọ́n ti máa ń pè é ní callos a la madrileña.
|
Caparrones
|
|
Spain (La Rioja)
|
Sausage
|
Stew made of caparrón (a variety of red kidney beans) and a spicy chorizo sausage
|
Caponata
|
|
Italy (Sicily)
|
Vegetarian
|
Ọbẹ̀ ẹ̀fọ́
|
Capra e fagioli
|
|
Italy (Liguria)
|
Ẹran ewúrẹ́
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran ewúrẹ́, àti àwọn ohun èlò mìíràn
|
Carbonada
|
|
Argentina, Uruguay
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ yìí gbajúmọ̀ ní Argentina àti Uruguay
|
Carbonade flamande
|
|
Belgium, France
|
Ẹran màálù
|
ọbẹ̀ tí a máa ń sè pẹ̀lú ẹran màálù àti àwọn ohun èlò ìsebẹ́ mìíràn
|
Carne mechada
|
|
ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ ẹrán àwọn Latin American
|
Cassoulet
|
|
France (Languedoc)
|
Adìẹ àti sausage
|
Oúnjẹ àwọn ará France èyí tí ó kún fún ẹran bíi ti ẹlẹ́dẹ̀
|
Cawl
|
|
United Kingdom (Wales)
|
Ẹran àgùntàn
|
Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn àti àwọn ẹ̀fọ́, àti àwọn ìsebẹ́ mìíràn.
|
Chairo
|
|
Bolivia
|
Ẹran màálù
|
Ẹran àti ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ pẹ̀lú chuños, àlùbọ́sà, kárọ́ọ̀tì, ànàmọ́, àgbàdo, ẹran màálù, abbl
|
Chakapuli
|
|
Georgia
|
ẹran àgùntàn
|
Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn tí ó gbajúmọ̀ tí a máa ń fi ata àti àlùbọ́sà sè
|
Chapea
|
|
Dominican Republic
|
Sausage
|
oúnjẹ ìbílẹ̀ àwọn Dominican Republic
|
Chicken mull
|
|
United States (South)
|
Fowl
|
ọbẹ̀ tí ó jẹ́ ti ìbílẹ̀ àwọn North Carolina àti Georgia
|
Chicken pastel
|
|
Philippines
|
Ṣíkìn tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
Ọbẹ̀ ẹran tí a le sè pẹ̀lú ṣíkìn tàbí ẹlẹ́dẹ̀
|
Chili con carne
|
|
United States (Texas)
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ ẹran tí ó kún fún ẹran màálù, ata àti àwọn ohun èlò mìíràn
|
Cholent
|
|
France
|
Ẹran màálù tàbí ẹran ṣíkìn
|
Ọbẹ̀ yìí jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń sè mọ́júmọ́. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ọbẹ̀ yìí pẹ̀lú oúnjẹ Shabbat. Àwọn èròjà rẹ̀ ni ẹran, àlùbọ́sà, ànàmọ́, ẹ̀wà àti barley. Wọ́n gbà pé láti inú hamin ti Sephardic Jews ni wọ́n ti rí i.
|
Chupe Andino
|
|
Andes
|
ẹran ìgbẹ́
|
Refers to various stews and soups that are prepared in Ó ń tọ́ka sí àwọn ọbẹ̀ tí wọ́n sè ní ẹkùn Andes Mountains ti ilẹ̀ South America
|
Chupín
|
|
Uruguay
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja pẹ̀lú àlùbọ́sà
|
Ciambotta
|
|
Italy
|
Vegetarian
|
Ọbẹ̀ tó dá lórí àwọn ẹ̀fọ́, ṣùgbọ́n tí ó le ní àwọn èròjà mìíràn
|
Cioppino
|
|
United States (San Francisco)
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja àwọn Italian-American, èyí tí wọ́n máa ń sè pẹ̀lú ẹja tí wọ́n bá sẹ̀sẹ̀ pa
|
Cocido lebaniego
|
|
Spain (Cantabria)
|
Ẹran ẹlẹ́dẹ̀ àti offal
|
Ọbẹ̀ yìí ládùn púpọ̀
|
Cocido madrileño
|
|
Spain (Madrid)
|
ẹran ẹlẹ́dẹ̀
|
Àwọn èròjà rẹ̀ ni chickpea tàbí ẹ̀wà garbanzo, èyí tí ó bá tóbi, tí a mọ̀ sí kabuli. Bẹ́ẹ̀ ni a máa ń da ẹ̀fọ́ mọ́ ọn.
|
Cocido montañés
|
|
Spain (Cantabria)
|
Ẹlẹ́dẹ̀ àti offal
|
ọbẹ̀ yìí ni a tún ń pè ní ọbẹ̀ highlander. A máa ń sè é pẹ̀lú white beans àti collard greens (berza).
|
Compote
|
|
|
ẹran ìgbẹ́
|
ọbẹ̀ ẹran ìgbẹ́ onírúurú
|
Coq au vin
|
|
France
|
Ṣíkìn
|
ọbẹ̀ ṣíkìn
|
Cotriade
|
|
France (Brittany)
|
Ẹja
|
Ọbẹ̀ ẹja tí ó jẹ́ onírúurú
|
Cozido/Cocido
|
|
Portugal Spain
|
Various
|
Oúnjẹ tí a sè pẹ̀lú onírúurú ẹran àti ẹ̀fọ́; ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan ló ní irúfẹ́ oúnjẹ wọn káàkiri Portugal àti Spain
|
Cream stew
|
|
Japan
|
Various
|
Oúnjẹ àwọn Japanese Yōshoku tí ó kún fún ẹran, bíi ṣíkìn tàbí ẹran ẹlẹ́dẹ̀, tí a dàpọ̀ mọ́ ẹ̀fọ́, àlùbọ́sà, kárọ́ọ̀tì, abbl
|
Daube
|
|
France (Provence)
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú ẹran màálù tí owó rẹ̀ kò wọ́n púpọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀fọ́ àti èròjà mìíràn.
|
Dillegrout
|
|
United Kingdom (England)
|
Fowl
|
Ọbẹ̀ ẹran ṣíkìn. [3]
|
Dimlama
|
|
Uzbekistan
|
Àgùntàn
|
Ọbẹ̀ tí a sè pelu àdàlù oríṣi ẹran, ànàmọ́, àlùbọ́sà, ẹ̀fọ́, àti nígbà mìíràn pẹ̀lú èso.
|
Dinuguan
|
|
Philippines
|
Offal
|
Ọbẹ̀ àwọn Filipino
|
Drokpa Katsa
|
|
Tibet
|
Offal
|
Ọbẹ̀ tí ó kún fún ìfun ẹran àti iyọ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà mìíràn.
|
Escudella i carn d'olla
|
|
Spain (Catalonia)
|
Sausage
|
Ọbẹ̀ tí ó kún fún pilota, bẹ́ẹ̀ ni a le lo oríṣi ẹ̀yà ẹran mìíràn
|
Étouffée
|
|
United States (Louisiana)
|
Seafood
|
Oúnjẹ àwọn Creole ti Louisiana èyí tí wọ́n sáábà máa ń fi jẹ ìrẹsì. Wọ́n máa ń pè é ní "smothered" ní French.
|
Fabada Asturiana
|
|
Spain (Asturias)
|
Ẹlẹ́dẹ̀
|
A máa ń sè é pẹ̀lú ẹ̀wà funfun àti apá ẹran ẹlẹ́dẹ̀.
|
Fabes con almejas
|
|
Spain (Asturias)
|
Seafood
|
A máa ń fi ọbẹ̀ yìí jẹ búrẹ́dì àti àwọn oúnjẹ mìíràn
|
Fahsa
|
|
Yemen
|
Àgùntàn
|
Ọbẹ̀ tí a sè pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà ara ẹran àgùntàn
|
Fårikål
|
|
Norway
|
Ẹran àgùntàn
|
Ọbẹ̀ ẹran àgùntàn tí ó máa ń ní ata àti àwọn èròjà amún-ọbẹ̀-dùn
|
Fasole cu cârnaţi
|
|
Romania
|
Sausage
|
ọbẹ̀ tí ó kó ẹ̀wà àti àwọn èròjà mìíràn sínú.
|
Feijoada
|
|
Brazil Portugal Uruguay
|
Ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ ẹ̀wà pẹ̀lú ẹran màálù tàbí ẹlẹ́dẹ̀ tí a le jẹ pẹ̀lú ẹ̀fọ́.
|
Fesenjān
|
|
Iran
|
Fowl
|
Ọbẹ̀ ẹran àti ẹja
|
Flaki
|
|
Poland
|
ẹran màálù
|
Ọbẹ̀ ẹran màálù àti àwọn ohun èròjà oríṣiríṣi
|
Főzelék
|
|
Hungary
|
Vegetarian
|
Ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ tí ó máa ń ki gan tí a máa ń jẹ pẹ̀lú ẹran.
|
Fricot
|
|
Canada (Acadia)
|
Various
|
Ọbẹ̀ yìí kún fún ànàmọ́, àlùbọ́sà àti àwọn onírúurú ẹran tí ó bá wà
|