Feijoada jẹ́ orúkọ tó gbajúmọ̀ tí wọ́n máa ń pe àwọn oúnjẹ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n máa ń sọ èdè Portuguese bíi Portugal, Brazil, Angola, East Timor, Mozambique, àti Macau, níbi tí wọ́n ti máa ń fi ẹran, ẹ̀wà dúdú,[2][3] pupa tàbí funfun sè tí a sì máa ń fi ìrẹsì kun.[4][5][6]
Ìtàn
Ẹran (ẹran ẹlẹ́dẹ̀) ọbẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀fọ́ tí a sì le tọpa rẹ̀ sí àwọn oúnjẹ àtijọ Róòmù.[7] [8]Oúnjẹ yìí gbajúmọ̀ ní Ìjọba Róòmù ó sì jẹ́ kí àwọn oúnjẹ mìíràn bíi cassoulet Faransé, cassoeula Milanese, Romanian fasole cu cârnați, àti fabada asturiana láti Àríwá ìwọ̀-oòrùn panish àti ido madrileño and olla podàtia, and the feijàti Minho province ní Àrìwá Portugal.[9][10]
Àwòrán
-
Seafood feijoada
-
Feijoada à brasileira
-
Feijoada à timorense
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "How to Make Feijoada, Brazil's National Dish, Including a Recipe From Emeril Lagasse". Smithsonian Magazine. Retrieved 2022-05-26.
- ↑ Brown, Sarah (March 17, 2017). "A Brief Introduction To Feijoada, Brazil's National Dish". https://theculturetrip.com/south-america/brazil/articles/a-brief-introduction-to-feijoada-brazils-national-dish. Retrieved July 27, 2021.
- ↑ Multicultural America: An Encyclopedia of the Newest Americans - Google Books p. 180.
- ↑ "Feijoada Recipe - How to Make Portuguese Feijoada | Hank Shaw". 5 December 2013.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2016-06-02. Retrieved 2016-02-09.
- ↑ Javier A. Galván (2020). Modern Brazil. ABC-CLIO. p. 313. ISBN 9781440860324. https://books.google.com/books?id=MkrzDwAAQBAJ&pg=PA313.
- ↑ "A feijoada não é invenção brasileira. Todo mundo acha que os inventores foram os escravos. Mas o prato já era apreciado na Europa desde os tempos do Império Romano". Super Interessante. Retrieved 10 September 2016.
- ↑ "A feijoada não é invenção brasileira. Todo mundo acha que os inventores foram os escravos. Mas o prato já era apreciado na Europa desde os tempos do Império Romano". Super Interessante. Retrieved 10 September 2016.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named Super Interessante3
- ↑ "O mito da feijoada, cuja real origem é lusitana". UOL educação. Retrieved 10 September 2016.