Wikimedia Commons jẹ́ ibùdó lórí Internet (Íńtánẹ́ẹ̀tì) fún ìkópamọ́ sí àwọn àwòrán, ìgboùn, àti àwọn fáílì amóhùnmáwòrán mìíràn. Ó jẹ́ iṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia Foundation.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.