Mustafa El Haddaoui

Mustafa El Haddaoui
Mustapha_el_Haddaoui
Personal information
OrúkọMustapha El-Hadaoui
Ọjọ́ ìbí28 Oṣù Keje 1961 (1961-07-28) (ọmọ ọdún 63)
Ibi ọjọ́ibíCasablanca, Morocco
Ìga1.81 m (5 ft 11 in)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1979–1985Raja Casablanca
1985–1987Lausanne Sports23(7)
1987–1988AS Saint-Étienne33(10)
1988–1990OGC Nice58(4)
1990–1993RC Lens84(14)
1993–1995Angers SCO65(9)
1996–1997SS Jeanne d'Arc
National team
1982–1994Morocco national football team47(10)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Mustafa El Haddaoui (Ni ede larubawa: مصطفى الحداوي) ni a bini ọjọ keji dinlọgbọn, óṣu july ni ọdun 1961 ni ilu Casablanca jẹ akọṣẹmọṣẹ agbabọọlu afẹsẹgba to ti fi ẹyinti[1].

Àṣèyọri

Mustapha lo ọpọlọpọ igba rẹ gẹgẹbi àkọṣẹmọṣẹ agbabọọlu afẹsẹgba ni ilu france. Arakunrin naa wa lara awọn elere to kopa ninu Cup FIFA agbaye to waye ti ọdun 1986 ati 1994[2]. Mustapha dije ninu Olympic ti Summer nibi to ti ṣoju fun órilẹ ede Morocco ni ọdun 1984[3][4]

Itọkasi

  1. Morocco - Record International Players
  2. FIFA World Cup
  3. 1984 Summer Olympics
  4. MUSTAFA EL HADDAOUI Career