Ìwé àwọn Onídàjọ́

Ìwé àwọn Onídàájọ́ sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti bí wọ́n ṣe dé ilẹ̀ Kénáánì, ikú Jóṣúà àti àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wọn sí Ọlọ́run.

Ìwé Onídàájọ́.

Itokasi