Ìwé Nehemíàh

Kíkọ́ odi Jerúsálẹ́mù

Ìwé Nehemáyà jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa àkókò kan nínú ìtàn àwọn Júù, ìyẹn bí i ìránṣẹ́ Ọlọ́run Nehemáyà ṣe padà sí Jerúsálẹ́mù láti bẹ̀rẹ̀ àti dárí kíkọ́ ilẹ̀ wọn àti títún ìgbàgbọ́ wọn tò, nítorí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ nínú ìgbèkùn Bábílónì ní.

Itokasi