Ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà ti a mo fun onibise bi Ijoba Apapo ile Naijiria tabi Ijoba Apapo ni soki unsise labe Ilana-Ibagbepo ile Naijiria ti odun 1999. Ijoba Apapo ni ijoba akoko ni to ni ase lori ile Naijiria ati awon ijoba awon Ipinle 36. Ibujoko re wa ni Abuja, ti se oluilu ile Nigeria. Ijoba apapo ile Naijiria koko waye ni ojo 1 osu kewa odun 1960 leyin ti Naijiria gba ilominira latowo Britani. Nigbana ilana-ibagbepo odun 1959 ni o da sile.
Ijoba ile Naijiria ni apa meta: apa apase, asofin ati asedajo
Itokasi