Public holidays in Nigeria

Nigeria .

Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi

Isinmi
Deeti Awon Akiyesi
New Year's Day 1 January Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi Ìbẹ̀rẹ̀ Ọdún tuntun.
Women's Day 8 March Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi láti fi bí àwọn Obìnrin ṣe ń kópa láwùjọ wọn jákè jádò àgbáyé.
Workers' Day 1 May Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún awon Osise jákè jádò àgbáyé.
Children's Day 27 May Àyájọ́ ọjọ ìsinmi fún àwọn ògo wẹẹrẹ.
Democracy Day 29 May Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún isejoba awa arawa ni orile ed Niajiria.
Independence Day 1 October Commemorates the Independence of Nigeria from Britain.
Christmas Day 25 December Christian holiday commemorating the birth of Jesus.
Boxing Day 26 December Christian holiday commemorating the day after Christmas.