Jésù ará Násárẹ́tì (c. 5 BC/BCE – c. 30 AD/CE[1]), tàbí Jésù Kírísítì tabi Jésù, jẹ́ ẹni tó ṣe kókó jùlọ, yàtọ̀ sí Ọlọ́run nínú Ẹ̀sìn Kírísítì, tí àwọn ẹlẹ́sìn náà gbà gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà Aráyé, èyí tí ó jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ ni Májẹ̀mú Láéláé nínú Bíbélì, tí gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣin Kíristi tàbí irú wọn gbà pé òun ni Ọmọ Ọlọ́run àti àwòrán Ọlọ́run tí ó jí dìde nínú ipò òkú.[4] Islamu gba Jesu gege bi woli ati Messiah.[5] Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀sìn mìíràn ni wọ́n tún tẹrí ba fún un lóríṣi ọ̀nà. Jésù jẹ́ ẹnìkan tó ṣe pàtàkì nínú ìtàn ọmọ ènìyàn.
Ẹ tún le ka
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ 1.0 1.1 1.2 Sanders (1993).p.11, p 249.
- ↑ "Our conclusion must be that Jesus came from Nazareth." Theissen, Gerd; and Merz, Annette. The historical Jesus: A comprehensive guide. Minneapolis: Fortress Press. 1998. Tr from German (1996 edition). p. 165. ISBN 978-0-8006-3123-9
- ↑ Eusebius, (trans. Cameron, Averil; Hall, Stuart G.). Life of Constantine. Oxford: Clarendon Press; New York : Oxford University Press, 1999. ISBN 978-0-19-814917-0
- ↑ Theologian and bishop Lesslie Newbigin says "the whole of Christian teaching would fall to the ground if it were the case that the life, death, and resurrection of Jesus were not events in real history but stories told to illustrate truths which are valid apart from these happenings." Newbigin, J. E. L. (1989). "The Gospel In a Pluralist Society". London: SPCK. p. 66.
- ↑ Abdulsalam, M. (19 February 2008). "Jesus in Islam". IslamReligion.com.