Open Amẹ́ríkà 2014 je idije tenis to waye ni ori papa tenis onisimenti ita gbangba. O sele ni papa idije USTA Billie Jean King National Tennis Center.