Wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ ti ìjọba apapọ̀ ní orílẹ̀-èdè China ní ọdún 2013 níbi ìpàdé Plenary Session of the 18th Central Committee of the Communist Party of China ẹlèkẹta iru rẹ̀. Nígbà tí ó di ọdún 2016, wọ́n ṣe agbékalẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ eti omi tàbí odò Three-River-Source National Park gẹ́gẹ́ bí àyẹ̀wò fún iṣẹ́ àkànṣe náà. Ọdún yí náà ni wọ́n dá ibùdó ìgbafẹ́ Fujian Wuyi Mountains National Park sílẹ̀, lẹ́yìn àwọn wọ̀nyí, oríṣiríṣi ibùdó ìgbafẹ́ bíi mẹ́jọ ni wọ́n tún ti da sílẹ̀. Lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyí,àwọn ibùdó ìgbafẹ́ tí ó wà ní orílẹ̀-èdè China lásìkò tí a ń ke àpilẹ̀kọ yí ti tó mọ́kànlá tí gbogbo wọn sì wà lábẹ́ àkóso ilé-iṣẹ́ ìjọba National Forestry and Grassland Administration.
Àwọn ibùdó ìgbafẹ́ náà nìwọ̀nyí
Ẹ tún lè wo
Àwọn ìtọ́ka sí
Àdàkọ:NoteFoot
Àdàkọ:China topics