Àtòjọ àwọn ojú ọ̀nà rélùwéè ní orịlẹ̀-èdè China.
rail transport in China. Láti mọ̀ nípa àwọn tí wọ́n yára jùlọ, ẹ wo the high-speed network, ẹ sì lè wo àwọn tí wọ́n ń lo iná mọ̀nà-mọ́ná List of high-speed railway lines in China.
Èyí tí ó bẹ̀rẹ̀ láti Ẹkùn Àríwá-Gúsù
Apá Beijing-Harbin
Lára àwọn ọkọ̀ ojú-irin akérò ni Jingshan Railway, Shenshan Railway, Changda Railway|Changda Railway, Changchun-Shenyang Portion àti ọkọ̀ ojú-irin Changbin wà tí wọ́n sì ń pè wọ́n ní Jingha Railway (Beijing-Harbin).
Apá Ilà-Oòrùn
Apá Beijing-Shanghai
Jingshan Railway Beijing-tianjin Portion, Jingpu Railway ati Huning Railway àpapọ̀ wọn ni wọ́n ń pè ní ọkọ̀ ojú-irin akérò Jinghu Railway(京沪线) .
Apá Beijing-Kowloon
Jingjiu Railway ni ó ń lo ojú-ọ̀nà kan náà pẹ̀lú Guangmeishan Railway làárín Longchuan àti Dongguan. Bákan náà ni ó tún ń lo ojú-ọ̀nà kan náà pẹ̀lú Guangshen Railway láàrín Dongguan àti Shenzhen. Ó sì tún gba ẹnu ibodè East Rail line lọ sí Kowloon, ní ìlú Họ́ng Kọng.
Apá Beijing-Guangzhou
Apá Datong-Zhanjiang
Apá Baotou-Liuzhou
Apá Baoji-Kunming
Ẹkun Ìwọ̀ Oòrùn-Ìlà Oòrùn
Beijing-Lhasa
Yangtze River Valley
Ihà Gúsù
Àwọn ọ̀nà tí wọ́n já pọ̀ mọ́ra wọn lábẹ́lé ni
Ojú ọ̀nà agbègbè
Àwọn Rélùwéè tí wọ́n lo Èédú
Àwọn Ọ̀nà tí wọ́n já pọ̀ mọ́ ara wọn
Ojú ọ̀nà rélùwéè tẹ́lẹ̀
Àwọn àsopọ̀ ìta
Àdàkọ:Transport in China