Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́-àgbà tí ó ń ṣe kòkárí àti ìmójútó àwọn ilé Ìfowópamọ́ káràkátà lábẹ́ òfin Ìfowópamọ́ tí Ìjọba Àpapọ̀ gbé kalẹ̀ lọ́dún 1958, tí ó sìn bẹ̀rẹ̀ lọ́jọ́ kìíní oṣù keje ọdún 1959.[1] Ó. Jẹ́ Ilé-ìfowópamọ́ fún àwọn Ilé-ìfowópamọ́[2]. Gómìnà ní orúkọ oyè tí Adarí yànyàn tí ó máa ń darí Ilé Ìfowópamọ́-àgbà máa ń jẹ́. Godwin Emefiele ní Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́́lọ́wọ́.[2] Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan ló yàn án lọ́dún 2014, lẹ́yìn èyí, Ààrẹ Muhammadu Buhari tún ṣe àtúnyàn rẹ̀ lọ́dún 2018 fún sáà Elékejì. [3].
Àtòjọ Àwọn Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà
Àwọn wọ̀nyí ni Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ àgbà ti Nàìjíríà tí ó ti jẹ láti ọdún 1960 títí di àkókò yìí:[4]
Àwọn Ìtọ́kasí