Mallam Aliyu Mai-Bornu tí wọ́n bí ní ọdún 1919, tí ó sì ṣaláìsí lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù kejì ọdún 1970 (1919 - 23 February 1970) jẹ́ òkúná-gbòǹgbò onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ ajé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó jẹ́ Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́-àgbà tí Nàìjíríà.[1]