Hafsat Idris |
---|
|
Ọjọ́ìbí | Hafsat Ahmad Idris 14 Oṣù Keje 1987 (1987-07-14) (ọmọ ọdún 37) Shagamu, Nigeria |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Iṣẹ́ | Actress, Film Maker |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 2015–present |
---|
Notable credit(s) | Best known for her appearance in Barauniya |
---|
Àwọn ọmọ | 2 |
---|
Hafsat Ahmad Idris tí a tún mọ̀ sí Hafsat Idris (táa bí ní 14 Oṣù Keèje, Ọdún 1987),[1][2] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó maá n ṣiṣẹ́ lágbo òṣèré ti Kannywood. Eré àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ti kópa ni fíìmù Barauniya (2016).[3] Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jùlọ ní ọdún 2019.[4]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
Hafsat jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínẹ̀ Kánò, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n ìlú Ṣàgámù ní Ìpínẹ̀ KánòÌpínẹ̀ Ògùn ni wọ́n bi sí, níbẹ̀ náà ló sì dàgbà sí.[5][6] Ó ṣe àkọ́kọ́ ìfihàn rẹ̀ ní agbo òṣèré Kannywood nínu fíìmù táa pe àkọ́lé rẹ̀ ní Barauniya pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Ali Nuhu, àti Jamila Nagudu.[7][8]
Ní ọdún 2018, ó dá ilé-iṣẹ́ agbéréjáde sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ramlat Investment. Ilé-iṣẹ́ náà ti gbé àwọn eré bi mélòó kan jáde ní ọdún 2019 tí ó fi mọ́ fíìmù Kawaye, èyítí òun àti àwọn òṣèré míràn bíi Ali Nuhu àti Sani Musa Danja dì jọ kópa nínu rẹ̀.[9]
Àwọn ìyẹ́sí tí ó ti gbà
Ọdún
|
Ẹ̀ye
|
Ẹ̀ka
|
Èsì
|
2017
|
City People Entertainment Awards
|
Most Promising Actress[10]
|
Wọ́n pèé
|
2018
|
City People Entertainment Awards
|
Best Actress [11]
|
Gbàá
|
2019
|
City People Entertainment Awards
|
Best Actress
|
Gbàá
|
2019
|
City People Entertainment Awards
|
Face of Kannywood
|
Gbàá
|
Àkójọ àwọn eré tí ó ti kópa
Hafsat ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù tó fi mọ́ àwọn wọ̀n yìí:[12]
Àkọ́lé
|
Ọdún
|
Biki Buduri
|
ND
|
Furuci
|
ND
|
Labarina
|
ND
|
Barauniya
|
2015
|
Makaryaci
|
2015
|
Abdallah
|
2016
|
Ta Faru Ta Kare
|
2016
|
Rumana
|
2016
|
Da Ban Ganshi Ba
|
2016
|
Dan Almajiri
|
2016
|
Haske Biyu
|
2016
|
Maimunatu
|
2016
|
Mace Mai Hannun Maza
|
2016
|
Wazir
|
2016
|
Gimbiya Sailuba
|
2016
|
Matar Mamman
|
2016
|
Risala
|
2016
|
Igiyar Zato
|
2016
|
Wata Ruga
|
2017
|
Rariya
|
2017
|
Wacece Sarauniya
|
2017
|
Zan Rayu Da Ke
|
2017
|
Namijin Kishi
|
2017
|
Rigar Aro
|
2017
|
Yar Fim
|
2017
|
Dan Kurma
|
2017
|
Kawayen Amarya
|
2017
|
Dokita Surayya
|
2018
|
Algibla
|
2018
|
Ana Dara Ga Dare Yayi
|
2018
|
Mata Da Miji
|
2019
|
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Hafsa Idris [HausaFilms.TV - Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. Retrieved 22 May 2019.
- ↑ Lere, Muhammad (17 December 2016). "Getting married is my priority – Kannywood actress, Hafsat Idris - Premium Times Nigeria". Premium Times. Retrieved 22 May 2019.
- ↑ Ismail, Kamardeen; Ikani, John; Dauda, Aisha (13 July 2018). "6 hot Kannywood actresses who are still single". Daily Trust. Archived from the original on 15 July 2020. Retrieved 15 July 2020.
- ↑ "Kannywood Winners Emerge @ 2019 City People Movie Awards". City People Magazine. City People Magazine. 14 October 2019. Retrieved 15 July 2020.
- ↑ "Hafsa Idris Biography - Age". MyBioHub. 2 June 2017. Retrieved 15 July 2020.
- ↑ Adamu, Muhammed (30 January 2017). "Hafsat Ahmad Idris: Epitome of hardwork, resilient actress". Blueprint. Retrieved 22 May 2019.
- ↑ "Ba zan iya fitowa karuwa a fim ba - Inji Hafsat Barauniya". Gidan Technology Da Media (in Èdè Árábìkì). Archived from the original on 2020-11-16. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ Nwafor; Nwafor. "10 Kannywood beauties rocking the movie screens - Events Chronicles". https://eventschronicles.com/ (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-07-15. Retrieved 2020-09-24.
- ↑ Muhammed, Isiyaku (24 September 2019). "Hafsat Idris hits one million followers on Instagram". Daily Trust. Retrieved 15 October 2019.
- ↑ People, City (11 September 2017). "2017 City People Movie Awards (Nominees For Kannywood)". City People Magazine. Retrieved 22 May 2019.
- ↑ People, City (24 September 2018). "Winners Emerge @ 2018 City People Movie Awards". City People Magazine. Retrieved 15 October 2019.
- ↑ "Hafsa Idris Biography | Age | Wikipedia | Pictures". 360dopes. 30 August 2018. Retrieved 22 May 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]