Sani Musa Danja |
---|
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kẹrin 1973 (1973-04-20) (ọmọ ọdún 51) Fagge, Kano, Nigeria[1] |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
---|
Iṣẹ́ | Òṣèré orí-ìtàgé, Olùgbéré-jáde, Adarí eré àti Singer, Alájótà |
---|
Olólùfẹ́ | Mansura Isa |
---|
Àwọn ọmọ | 4 |
---|
Sani Musa Abdullahi, tí wọ́n tún mọ̀ sí Sani Danja tàbí Danja tí wọ́n bí ní ogúnjọ́ oṣù Kẹrin ọdún 1973 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, alájótà àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[2] Ó kópa nínú àwùjọ Kannywood àti Nollywood.[3] Ní oṣù Kẹ́rin ọdún 2018, tí ó jẹ́ Etsu Nupe , Yahaya Abubaka, wé láwàní fun gẹ́gẹ́ bí Zakin Arewa. [4][5]
Iṣẹ́ rẹ̀
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ eré ìtàgé Hausa ní ọdún 1999 nínú eré Daliba.
Danja ti gbé àwọn eré ó sì ti darí àwọn eré bíi: Manakisa, Kwarya tabi Kwarya, Jaheed, Nagari, Wasiyya, Harsashi, Gidauniya, Daham, Jarida, Matashiya, àti àwọn mìíràn. Danja di ìlú-mòọ́ká ní ọdún 2012 nínú eré Daughter of the River. [6][7]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
Sani ti kópa nínú eré , ó sì ti gbé eré jáde ó sì ti darí eré Kannywood àti Nollywood. Lárà rẹ̀ ni :[8]
Àkọ́lé eré
|
Ọdún
|
Yar agadez
|
2011
|
A Cuci Maza
|
2013
|
Albashi (The salary)
|
2002
|
Bani Adam
|
2012
|
Budurwa
|
2010
|
Da Kai zan Gana
|
2013
|
Daga Allah ne'’ (Is from the God)
|
2015
|
Daham
|
2005
|
Dan Magori
|
2014
|
Duniyar nan
|
2014
|
Fitattu
|
2013
|
Gani Gaka
|
2012
|
Gwanaye
|
2003
|
Hanyar Kano
|
2014
|
Kukan Zaki (The lion's cry)
|
2010
|
The other side
|
2016
|
Buri uku a duniya (Three wishes in the world)
|
2016
|
Àwọn Ìtọ́kasí