2022 Nigeria floods

Àwòrán àwọn ènìyàn tó ṣàgbákò àgbàrá òjò

 

Àgbàrá tó wáyé ní Nàìjíríà ti ọdún 2022 kan ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àgbègbè ní orílẹ̀-èdè náà. Láti inú dẹ́tà ti ìjọba àpapọ̀, àgbàrá náà ti sọ ènìyàn tó ń lọ bíi 1.4 million di aínìnílélórí, ó ti pa ènìyàn 603, ó ṣe ènìyàn 2400 léṣe. Àwọn ilé tó wo ń lọ bíi 82,035, àwọn ilè tó ń lọ bíi 332,327 ló sì ti bàjẹ́.[1]

Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé àgbàrá máa ń wáyé dáadáa ní orílẹ̀-èdè Nàijiria, àmọ́ àgbàrá ọdún yìí ló léwu jù lọ, láti ìgbà tí èyí tó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2012 wáyé. [2] Ní oṣù kẹwàá, àwọn ilé tó ń lọ bíi 200,000 ni àgbàrá yìí bàjẹ́. Ní ọjọ́ keje oṣụ̀ kẹwàá, ọkọ-ojú-omi kan tó ń gbẹ́ àwọn ènìyàn tó ń sá àsálà fún ẹ̀mí wọn ló dojúdé, tih ó sì fa ikú ènìyàn 76, ìyẹn mẹ́rìnlélọ́gọ́rin.[3]


Ohun tó fa àgbàrá náà ni òjò wẹliwẹli kan tó pọ̀, ìyípadà tó dé bá afẹ́fẹ́, àti omi tó ṣí sílẹ̀ ní Lagodo DamCameroon, èyí tó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án. Àgbàrá náà ṣàkóbá sí orílẹ̀-èdè Naijiria, Niger, Chad àti àwọn agbègbè rẹ̀, tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ìgbà oòrùn ní ọdún 2022, tí ó sì parí ní oṣù kẹwàá.[4][5]

Àgbàrá náà ní agbègbè tó ti ṣẹlẹ̀

Ìpínlẹ̀ Adamawa

Ní ìparí oṣù kẹjọ, ọ̀pọ̀ àgbàrá ní ipinle Adamawa fa ikú ènìyàn mẹ́wàá, ó sì da ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé rú.[6]

Ìpínlẹ̀ Anambra

Ní ọjọ́ keje oṣụ̀ kẹwàá, ọdún 2022, ènìyàn 76 ló sì sínú omi lẹ́yìn tí ọkọ̀-ojú-omi dojúdé sínú odo.[7]Àkúnwọ́nsílẹ̀ odò Niger àti ọ̀pọ̀ òjò tó rọ̀ ló jẹ́ kí omi yẹn kún ní àkúnkù. Àwọn ìlú tó wà ní agbègbè omi ni àgbàrá bàjẹ́.[8]

Ilé-ìjọsìn alájà mẹ́ta, ìyẹn Madonna Catolic Churn ní Iyiowa dà wó látàrí àgbàrá náà, tó wáyé ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹwàá.[9]

Awọn ibudo IDP 28 wa ni ipinlẹ Anambra, nibiti awọn olufaragba iṣan omi ti wa ni aabo ati ti itọju lakoko awọn akoko pajawiri iṣan-omi. [10] Láti dínkù wàhálà àti ìgbènijà àwọn ẹni tí àgbàrá yìí ba ilé wọn jẹ́, wọ́n gbé àwọn kám̀pù kéréje kéréje kalẹ̀ sí àwọn agbègbè lóríṣiríṣi ìpínlẹ̀ náà.

  • Crowther Memorial Primary School Camp, Onitsha, Ipinle Anambra: Ibùdó yìí ni àwọn olùfaragbá àgbàrá náà, láti oríṣiríṣi agbègbè tí ó wà pẹ̀lú Mmiata-Anam, Umudora-Anam, Nzam, Ukwala, Inoma, àti Owele láti apá Ìwọ̀-oòrùn Ìpínlẹ̀ Anambra. Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tó wà ní àgọ́ náà jẹ́ nǹkan bí ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún [1,800]. Àwọn aláboyún márùn-ún bí ọmọ wọn ní ibùdó ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Crowther Memorial, Onitsha. Síbẹ̀síbẹ̀, wọ́n mú wọn lọ sí ilé-ìwòsàn gbogbogbo, ní Onitsha fún ìtọ́jú tó dára lẹ́yìn ìbímọ ní ibùdó IDP.[11]
  • Agbegbe Onitsha North Council Area Internally Displaced People (IDP): Ibudo IDP ti gbe awọn eniyan bi 400 lati Umuoba Anam ati Ekpe Nneyi, Umueri ni Agbegbe Igbimọ Ila-oorun Anambra. Awọn olufaragba iṣan omi tun wa lati Ipinle Delta ni wọn gbe ni ibudó nibiti wọn ti pin awọn ohun elo iranlọwọ ati awọn ohun elo miiran.[12][13]
  • Ibudo ijoba ibile Ogbaru: Eyi wa ni agbegbe Atani. Bi o ti wu ki o ri, ikun omi de ti o si rì olu ileeṣẹ ijọba ibilẹ naa nigba ti awọn ẹlẹwọn wa nibẹ. Awọn eniyan wa ni ayika pẹlu awọn ọkọ oju omi ati gbe awọn olufaragba iṣan omi ti o ni idẹkùn kuro. O di ajalu meji fun awọn olufaragba iṣan omi.[14]
  • IDP ibùdó Umueri[15]
  • IDP ibùdó Aguleri[16]

Ìpínlẹ̀ Jigawa

Àgbàrá náà ti kọlu Ipinle Jigawa láti oṣù kẹjọ sí oṣù kẹsàn-án, níbi tí àwọn ènìyàn bíi méjìléláàádọ́rùn-ún (92) ti kú.[17]

Ìpínlẹ̀ Kano

Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún, Nigerian Meteorological Agency fún àwọn ènìyàn ní ìkìlọ̀ nípa àgbàrá omi tó máa ṣẹlẹ̀ ní ìpinlẹ̀ náà.

Ìpínlẹ̀ Kogi

Lokoja, tí ó wà ní ibi ìpàdé àwọn odò Benue àti Niger, wà láàrin àwọn agbègbè tí ó ní ipa tí ó burú jù látàrí ìṣàn omi.[18]

Ìpínlẹ̀ Niger

Mariga, ipinle Niger, òkú tí omi ṣàn lọ kúrò níbi ìtẹ́ òkú jú 1,500 lọ.[19] Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba sọ pé òkú 650 ni wọ́n rí padà, tí wọ́n sì padà sin.[20]

Ìpínlẹ̀ Yobe

Àgbàrá omi ńlá wáyé ni Ipinle Yobe ní oṣù keje tí ó sì pa ènìyàn mẹ́rin.[21]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. Oguntola, Tunde (2022-10-17). "2022 Flood: 603 Dead, 1.3m Displaced Across Nigeria – Federal Govt" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-07. 
  2. Maclean, Ruth (17 October 2022). "Nigeria Floods Kill Hundreds and Displace Over a Million". The New York Times. https://www.nytimes.com/2022/10/17/world/africa/nigeria-floods.html. 
  3. "Nigerian boat accident death toll rises to 76, president says". The Guardian. 9 October 2022. 
  4. "Nigeria floods: 'Overwhelming' disaster leaves more than 600 people dead" (in en-GB). BBC News. 2022-10-16. https://www.bbc.com/news/world-africa-63280518. 
  5. "Nigeria floods 80 times more likely with climate change" (in en). AP NEWS. November 16, 2022. https://apnews.com/article/floods-science-africa-nigeria-climate-and-environment-7972ff1cba1134cc80219acff1a51d42. 
  6. Davies, Richard (26 August 2022). "Nigeria – 10 Dead After Severe Flash Floods in Adamawa State". FloodList. 
  7. "Nigerian boat accident death toll rises to 76, president says". The Guardian. 9 October 2022. 
  8. "Anambra, Delta Deadly Floods: 70-yr-old killed while sleeping in submerged home". Vanguard. 16 October 2022. https://www.vanguardngr.com/2022/10/anambra-delta-deadly-floods-70-yr-old-killed-while-sleeping-in-submerged-home/. 
  9. Obianeri, Ikenna (9 October 2022). "Conflicting figures trail Anambra boat crash, church collapses". Punch.ng. https://punchng.com/conflicting-figures-trail-anambra-boat-crash-church-collapses/. 
  10. Agency Report (2018-02-18). "No killing at IDP camps in Anambra – Official". Premium Times. Archived on 2023-02-26. Error: If you specify |archivedate=, you must also specify |archiveurl=. https://www.premiumtimesng.com/news/more-news/458098-no-killing-at-idp-camps-in-anambra-official.html?tztc=1. 
  11. "Five women give birth in Anambra IDP camp". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-24. Retrieved 2023-02-26. 
  12. "Deltans flood IDP camps in Anambra – The Sun Nigeria". sunnewsonline.com. Retrieved 2023-02-26. 
  13. "Soludo visits IDP camps, seeks support for displaced persons". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Nigeria. 2022-10-06. Archived from the original on 2023-02-26. Retrieved 2023-02-26. 
  14. Maduforo, Okey (2022-10-20). "Lamentations of flood victims in Anambra IDP camps". New Telegraph (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-26. 
  15. "Flood: Metchie Decries Absence of NEMA, SEMA in Anambra IDP Camps – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2023-02-26. 
  16. "Flood: Metchie Decries Absence of NEMA, SEMA in Anambra IDP Camps – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2023-02-26. 
  17. Davies, Richard (22 September 2022). "Nigeria – 300 Dead, 100,000 Displaced as Government Warns of Worsening Floods". FloodList. 
  18. Jones, Mayeni (14 October 2022). "Nigeria floods: Braving the rising waters in Kogi state". BBC News. https://www.bbc.com/news/world-africa-63262391. 
  19. Ibrahim Garba Shuaibu (22 September 2022). "Floods sweep away 1,500 corpses from cemetery in northern Nigeria". Anadolu Agency. 
  20. Empty citation (help) 
  21. Davies, Richard (20 July 2022). "Nigeria – Floods Wreak Havoc in Yobe State". FloodList. 

Read other articles:

Artikel ini perlu diwikifikasi agar memenuhi standar kualitas Wikipedia. Anda dapat memberikan bantuan berupa penambahan pranala dalam, atau dengan merapikan tata letak dari artikel ini. Untuk keterangan lebih lanjut, klik [tampil] di bagian kanan. Mengganti markah HTML dengan markah wiki bila dimungkinkan. Tambahkan pranala wiki. Bila dirasa perlu, buatlah pautan ke artikel wiki lainnya dengan cara menambahkan [[ dan ]] pada kata yang bersangkutan (lihat WP:LINK untuk keterangan lebih lanjut...

 

Isotop utama plutonium Iso­top Peluruhan kelim­pahan waktu paruh (t1/2) mode pro­duk 238Pu renik 87,74 thn SF – α 234U 239Pu renik 2,41×104 thn SF – α 235U 240Pu renik 6500 thn SF – α 236U 241Pu sintetis 14 thn β− 241Am SF – 242Pu sintetis 3,73×105 thn SF – α 238U 244Pu renik 8,08×107 thn α 240U SF – lihatbicarasunting Plutonium (94Pu) adalah sebuah unsur buatan, kecuali sebagai jumlah renik yang dihasilkan dari penangkapan neutron oleh ura...

 

PaléoichnologieLe Ciampate del Diavolo (en) (littéralement le « sentier du Diable ») sur les pentes du volcan Roccamonfina (en). Considérées par le folklore local comme les traces de pas du Diable, seule créature capable de marcher dans la lave, ce sont en réalité des empreintes fossiles humaines.Partie de Ichnologie (en), paléontologiemodifier - modifier le code - modifier Wikidata La paléoichnologie (du grec : palaios, ancien ; ιχνος, ikhnos, em...

Botanic garden in London, England This article is about the botanical gardens in south-west London. For the non-departmental public body, see Royal Botanic Gardens, Kew. For other uses, see Kew Gardens (disambiguation). Kew GardensA view across the gardens to the Palm House in Kew Gardens, in London, EnglandTypeBotanicalLocationLondon Borough of Richmond upon Thames, EnglandCoordinates51°28′44″N 00°17′37″W / 51.47889°N 0.29361°W / 51.47889; -0.29361Area121 ...

 

يانوس كوروين-ميكي (بالبولندية: Janusz Korwin-Mikke)‏  معلومات شخصية الميلاد 27 أكتوبر 1942 (82 سنة)  وارسو  مواطنة بولندا  عدد الأولاد 8   مناصب عضو في البرلمان الأوروبي   عضو خلال الفترة1 يوليو 2014  – 28 فبراير 2018  انتخب في انتخابات البرلمان الأوروبي 2014  الدائرة الإنت...

 

В статье не хватает ссылок на источники (см. рекомендации по поиску). Информация должна быть проверяема, иначе она может быть удалена. Вы можете отредактировать статью, добавив ссылки на авторитетные источники в виде сносок. (23 февраля 2023) Эта статья опирается на источники...

Questa voce sull'argomento società calcistiche cipriote è solo un abbozzo. Contribuisci a migliorarla secondo le convenzioni di Wikipedia. AEK KoukliōnCalcio Segni distintivi Uniformi di gara Casa Trasferta Colori sociali Giallo, nero Dati societari Città Kouklia Nazione  Cipro Confederazione UEFA Federazione CFA Fondazione 1968 Scioglimento2014 Stadio Pafiako Stadium(9.500 posti) Palmarès Si invita a seguire il modello di voce L'Athlītikī Enōsī Koukliōn (in greco Αθλ�...

 

† Человек прямоходящий Научная классификация Домен:ЭукариотыЦарство:ЖивотныеПодцарство:ЭуметазоиБез ранга:Двусторонне-симметричныеБез ранга:ВторичноротыеТип:ХордовыеПодтип:ПозвоночныеИнфратип:ЧелюстноротыеНадкласс:ЧетвероногиеКлада:АмниотыКлада:Синапсиды�...

 

Mitra Waterboom & Toys Wahana di Mitra Waterboom & Toys Informasi Lokasi Jepara. Negara  indonesia Pengelola CV. Mitra Waterboom & Toys Awal pembangunan 2011 Penyelesaian 2012 Jenis objek wisata Wisata Air Gaya Alam Fasilitas  • Waterboom • Kolam Renang • Kid's Pool • Mandi Bola • Perosotan • Air Mancur • dll Mitra Waterboom & Toys adalah tempat wisata yang terdapat di Kabupaten Jepara yang terdapat di Desa Bangsri. Mitra ...

Washington Informasi pribadiNama lengkap Washington Stecanela CerqueiraTanggal lahir 1 April 1975 (umur 49)Tempat lahir Brasília, BrasilPosisi bermain PenyerangKarier senior*Tahun Tim Tampil (Gol)1994-1996 Caxias do Sul 1997 Internacional 1998 Ponte Preta 1998-1999 Caxias do Sul 1999-2000 Paraná 2000-2002 Ponte Preta 2002-2003 Fenerbahçe 2004 Atlético Paranaense 2005 Tokyo Verdy 2006-2007 Urawa Reds 2008 Fluminense 2009-2010 São Paulo 2010 Fluminense Tim nasional2001-2002 Brasil 9 ...

 

Election for governor of the U.S. state Indiana For related races, see 2008 United States gubernatorial elections. 2008 Indiana gubernatorial election ← 2004 November 4, 2008 2012 →   Nominee Mitch Daniels Jill Long Thompson Party Republican Democratic Running mate Becky Skillman Dennie Oxley Popular vote 1,563,885 1,082,463 Percentage 57.8% 40.1% County resultsDaniels:      40–50%      50–60%  ...

 

Norwegian metal band ArcturusArcturus in 2016Background informationOriginNorwayGenres Avant-garde metal symphonic black metal progressive metal melodic black metal[1] (early) Years active1991–2007, 2011–presentLabelsCentury Media, Music for Nations, Candlelight, The End, Jester, Season of MistMembersSteinar Sverd JohnsenJan Axel BlombergHugh MingayKnut Magne ValleICS VortexPast members(see below)Websitewww.arcturus.no Simen „ICS Vortex“ Hestnæs at Party.San 2016 Steinar „S...

CW TV station in Salem, Oregon This article needs additional citations for verification. Please help improve this article by adding citations to reliable sources. Unsourced material may be challenged and removed.Find sources: KRCW-TV – news · newspapers · books · scholar · JSTOR (September 2014) (Learn how and when to remove this message) KRCW-TVATSC 3.0 stationSalem–Portland, Oregon–Vancouver, WashingtonUnited StatesCitySalem, OregonChannelsDigita...

 

Центральний державний архів вищих органів влади та управління України(ЦДАВО України) Дата відкриття 1920 Кількість фондів 3338 Кількість одиниць зберігання 2 083 049 (одиниць зберігання),19 368 (од. зб. науково-технічної документації) Хронологічні рамки документів 1917...

 

2016年美國總統選舉 ← 2012 2016年11月8日 2020 → 538個選舉人團席位獲勝需270票民意調查投票率55.7%[1][2] ▲ 0.8 %   获提名人 唐納·川普 希拉莉·克林頓 政党 共和黨 民主党 家鄉州 紐約州 紐約州 竞选搭档 迈克·彭斯 蒂姆·凱恩 选举人票 304[3][4][註 1] 227[5] 胜出州/省 30 + 緬-2 20 + DC 民選得票 62,984,828[6] 65,853,514[6]...

William Waddington Duta Besar Prancis untuk Britania RayaMasa jabatan1883-1893PendahuluPaul-Armand Challemel-LacourPenggantiAlphonse Chodron, baron de CourcelPerdana Menteri PrancisMasa jabatan4 Februari 1879 – 28 Desember 1879PendahuluJules DufaurePenggantiCharles de Freycinet Informasi pribadiLahir11 Desember 1826Saint-Rémy-sur-AvreMeninggal13 Januari 1894(1894-01-13) (umur 67)ParisPartai politikTidak adaSuami/istriMathilde Lutteroth ​ ​(m. 1850;...

 

Winmarleigh is a civil parish in the Wyre district of Lancashire, England. It contains two listed buildings that are recorded in the National Heritage List for England. Both the listed buildings are designated at Grade II, the lowest of the three grades, which is applied to buildings of national importance and special interest.[1] Other than the village of Winmarleigh, the parish is rural. The listed buildings are a public house and a church. Map all coordinates using OpenStreet...

 

Neighbourhood in North Lanarkshire, Scotland Human settlement in ScotlandCarbrainSouth Carbrain's Millcroft Road flats viewed from Cumbernauld railway stationCouncil areaNorth LanarkshireLieutenancy areaDunbartonshireCountryScotlandSovereign stateUnited KingdomPost townGLASGOWPostcode districtG67Dialling code01236PoliceScotlandFireScottishAmbulanceScottish UK ParliamentCumbernauld, Kilsyth and Kirkintilloch East (UK Parliament constituency)Scottish Parliamen...

Coalition of different political groupings For other uses, see Popular Front (disambiguation). The neutrality of the style of writing in this article is disputed. Please do not remove this message until conditions to do so are met. (November 2020) (Learn how and when to remove this message) Cartoon depiction of a popular front in the Romanian leftist and anti-fascist newspaper Cuvântul Liber, 1935 Part of the Politics seriesParty politics Political spectrum Left-wing Far-leftCentre-left Cent...

 

此條目需要补充更多来源。 (2022年5月20日)请协助補充多方面可靠来源以改善这篇条目,无法查证的内容可能會因為异议提出而被移除。致使用者:请搜索一下条目的标题(来源搜索:陶笛 — 网页、新闻、书籍、学术、图像),以检查网络上是否存在该主题的更多可靠来源(判定指引)。 此條目偏重在某些見解、事件或爭議上。 (2024年1月4日)請協助建立更平衡的陳述以符...