Ìwàìbàjẹ́ olóṣèlú ki se isele oni to gba Naijiria kankan. Lati igba idasile isejoba ilu lorilede ni ejo ilokulo onibise awon alumoni fun isola adani.[1] Iloke isejoba ilu ati ibapade epo ati efuufu onidanida ni awon isele meji to fa ogunlogo iwaibaje lorilede.
Itokasi
- ↑ The Storey Report. The Commission of Inquiry into the administration of Lagos Town Council