Àwọn ẹ̀yà Ìgbò (English /ˈiːboʊ/EE-boh,[2][3] also US /ˈɪɡboʊ/;[4][5] tí wọ́n tún ń pè níYíbà[6][7][8][9] tàbí Heebo;[10]
tí àpèjẹ́ wọn ń jẹ́ Ṇ́dị́ ÌgbòÀdàkọ:IPA-ig) ni wọ́n jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní àrin gbùngbùn ìlà Oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Kò sí ẹni tó mọ pàtó ibi tí àwọn ẹ̀yà yí ti wá ṣáájú kí wọ́n tó kóra jọ sí ìletò tí wọ́n wà lóní.[11] Ilẹ̀ Ìgbò pín sí ọ̀nà méjì, àkọ́kọ́ èyí tí ó wà ní apá àríwá tí ó wà ní apá Odò Ọya tó jẹ́ èyí tó tobi jù ti ẹ̀ẹ̀kejì apá ìlà Oòrun. [12][13] Àwọn ẹ̀yà ìgbà Ìgbò jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà tí ó pọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.[14]
Ohun tí wọ́n mọ àwọn èyà yí mọ̀ ni iṣẹ́ ọnà, iṣẹ́ àgbẹ̀ àti iṣẹ́ òwò ṣíṣe. Lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí wọ́n sábà ma ń gbìn jù ni Iṣu,[16] bẹ̀ẹ́ ni wọ́n ma ń gbin ẹ̀gẹ́ àti taro.[17]
Àwọn Ìtọ́ka sí
↑[1]Archived 2018-01-29 at the Wayback Machine. at CIA World Factbook: Nigeria country profile "Igbo 20.2%" out of a population of 214 million (2020 estimate). There are over 10 million Igbo living outside Nigeria. They are significant Igbo populations residing in most African countries and they are found in all corners of the globe, no matter how remote.
↑Slattery, Katharine. "The Igbo People – Origins & History". www.faculty.ucr.edu. School of English, Queen's University of Belfast. Retrieved April 20, 2016.