Àyọkà yìí ṣe àtòjọ orúkọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà láti ìgbà tí wọ́n dá ipò náà sílẹ̀ ní ọdún 1961 (nígbà Ìjídìde àwọn ará Rùwándà), títí di òní. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ ṣe lànà rẹ̀, iṣẹ́ Ààrẹ ni gẹ́gẹ́bí olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Rwanda, ó sì ní agbára aláṣe tó pọ̀.[2] Wọ́n dìbò yan sí ipò ààrẹ yìí fún ọdún méje,[3] Ààrẹ yíò si yan Alákóso Àgbà àti gbogbo àwọn ará Kábínẹ́ẹ̀tì rẹ̀.[4]
Àwọn mẹ́rin ló ti jẹ Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà (láì ka àwọn Adípò Ààrẹ). Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Paul Kagame, láti 24 March 2000.
Key
- Political parties
- Other factions
- Status
List of officeholders
Latest election
Itokasi
|
---|
| |
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found