Akojo awon alamojuto ati awon gomina Ipinle Katsina. Ipinle Katsina je didajo ni 1987 nigbati o je yiyo kuro ninu Ipinle Kaduna.