Coordinates: 38°54′00″N 77°2′39″W / 38.90000°N 77.04417°W / 38.90000; -77.04417
Àjọ Ètò Owó Káríayé (AEOK; International Monetary Fund, IMF) je agbajo kariaye to n mojuto sistemu inawo lagbaye nipa titele awon ipinu makroekonomi awon orile-ede omo egbe re, agaga awon ipinu to nipa lori osuwon pasiparo owo ati ibamu awon isanwo. O je didasile lati se imuro sinsin awon osuwon pasiparo owo kariaye ati lati segbowo idagbasoke.[1] Oluile-ise re wa ni Washington, D.C., Amerika.
Itokasi