Tiwalola Olanubi Jnr tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdílọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ olókowò ara ẹni lórí oúnjẹ, oníṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]
Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣ́ẹ́ Dotts Media House èyí tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó lààmì-laaka ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ nípa digital marketing, òun náà tún ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ '' Zarafet Loaves'' tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ búrẹ́dì tí ó wà ní ilú Èkó, òun náà tún ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Trendupp Africa. Òun náà tún ni Olóòtú àgbà ìwé ''Nigerian Influencer Marketing Report'' (NIMR).[4]̀[5]
Àwọn ìtọ́ka sí
- ↑ Chinyere Eze (10 May 2019). "Young Nigerian Entrepreneur, Tiwalola Olanubi an exemplary to his peers". News Direct 5 ( 127): 4.
- ↑ Francis Okoliko (August 27, 2019). "Tiwalola Olanubi Jnr Nominated for Future Award 2nd time in three years". Daily Asset 6 ( 215): 29. ISSN 2616-1036.
- ↑ Admin. "TIWALOLA OLANUBI JNR – OUR REBRAND NIGERIA AMBASSADOR | Rebrand Nigeria Campaign" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-04. Retrieved 2020-06-04.
- ↑ "Dotts Media emerges best digital, marketing influencer in 2019". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-27. Retrieved 2021-05-26.
- ↑ BellaNaija.com (2020-03-16). "Tiwalola Olanubi Jnr. of DottsMediaHouse is Our #BellaNaijaMCM this Week!". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-26.