The Set Up jẹ́ fíìmù ọdún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó dá lórí ìwà-ọ̀daràn, tó jáde ní ọdún. Niyi Akinmolayan ni olùdarí fíìmù náà.[2][3] Lára àwọn tí wọ́n lò nínú fíìmù yìí ni Dakore Akande, Adesua Etomi àti Kehinde Bankole.[4] Ìtàn náà dá lórí arábìnrin kan tó jáwọ́ nínú ìwà pẹ̀lẹ́ rẹ̀ tó wá bẹ̀rẹ̀ sí ní wùwà ọ̀daràn. Wọ́n ṣàgbéjáde fíìmù yìí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹjọ, ọdún 2019. Ó gba oríṣiríṣi àríwísí, tí àwọn kan sì gbẹ́nu àtẹ́ lù ú nítorí àhúnpọ̀ ìtàn náà lọ́jú, tí ó sì wọnú ara wọn.[5][6] Despite the mixed reception, the film became a success at the box office.[7] It was also streamed via Netflix on 22 April 2020.[8][9]
Àwọn akópa
Àwọn ìtọ́kasí