Christopher George Latore Wallace tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1972, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹta ọdún 1997 (May 21, 1972 – March 9, 1997) jẹ́ olórin tàkasúfèé ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bí Biggie Smalls lẹ́yìn tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ (Let's Do It Again) lọ́dún 1975, àti Big Poppa, pẹ̀lú The Black Frank White, bẹ́ẹ̀ náà nínú sinimá àgbéléwò (King of New York),[1] sugbon gangan pelu oruko ori itage re The Notorious B.I.G..