Sósíálístì Káríayé (Socialist International) je agbajo kakiri aye awon egbe oloselu oseluarailu alawujo, sosialisti ati osise. O je didasile ni 1951.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.