Plazas de soberanía

Fáìlì:Plazasdesoberanía.png
The plazas de soberanía plus Ceuta, Melilla and Isla de Alborán.
Peñón de Vélez de la Gomera, seen from the Moroccan coast.

Plazas de soberanía ("places of sovereignty"), teletele bi "África Septentrional Española" (Spanish North Africa) tabi lasan bi "África Española" (Spanish Africa) je agbegbe orile-ede Spain ni North Africa to ni bode mo Morocco, ayafi awon ilu adawa Ceuta ati Melilla.



Itokasi