Muna (rapper)
Munachi Gail Teresa Abii Nwankwo jẹ́ olórin, akọrin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí telefision àti osere ni ìpínlè Nàìjíríà . Ó gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Imo ni Nàìjíríà.[1] Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀Wọn bíi sì ilẹ̀ Port Harcourt, ibẹ̀ ni ó sì gbé dàgbà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girl's College ni Abuloma. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Benson Idahosa University níbi tí ó tí ká International relations and Diplomacy.[2] ÌṣeÓ gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà ní ọdún 2007 ní ìgbà tí ó sì wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga.[3][4] Óun ló ṣe aṣojú fún Nàìjíríà nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni àgbáyé.[5] Ní ọdún 2009, òun àti ẹni tí ó gbé ìgbà o ròkè ní ọdún 2000 fún ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà, Matilda Kerry jọ ṣíṣe pọ̀ láti sọ̀rọ̀ nípa àrùn jẹjẹrẹ.[6] Munachi je olórin, orúkọ orí ìtàgé rẹ ni Babyrella kí ó tó padà wá yí sì Múná.[7] Ó ti kọ orin fún àwọn olórin bíi J Martins àti Waje. Ó sì má ṣe kópa nínú fíìmù fún àwọn olórin, ó wá nínú fíìmù Ifunaya tí àwọn P Square ṣe. Ni oṣù kẹfà ọdún 2010, Muna darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Ayọ̀ Shonaiya RMG company níbi tí ó tí ṣe àwọn orin rẹ̀ bíi The Goddess àti The hustler. [8][9][10][11] Ní ọdún 2011, Múná darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Unilever níbi tí ó tí ṣe àwòṣe fún Lux.[12] Ó ṣe atọkun fún eré orí telefision tí Malta Guinness Street Dance Africa.[13] Àwọn Ìtọ́kasí
Information related to Muna (rapper) |