Max Horkheimer |
---|
|
Orúkọ | Max Horkheimer |
---|
Ìbí | (1895-02-14)Oṣù Kejì 14, 1895 Stuttgart, Württemberg, Germany |
---|
Aláìsí | July 7, 1973(1973-07-07) (ọmọ ọdún 78) Nuremberg, Bavaria, Germany
|
---|
Ìgbà | 20th century philosophy |
---|
Agbègbè | Western Philosophy |
---|
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Critical Theory |
---|
Ìjẹlógún gangan | Social Theory, Counter-Enlightenment |
---|
Àròwá pàtàkì | Critical Theory, The Culture Industry, Authoritarian Personality, Eclipse of Reason |
---|
|
|
Max Horkheimer (February 14, 1895 – July 7, 1973) je amoye-aseoro-awujo omo Ju ara Jemani, to gbajumo fun ise re ninu irojinle alagbewo gege bi okan ninu 'Frankfurt School' fun iwadi awujo. Ninu awon iwe re pataki je The Eclipse of Reason (1947) ati eyi to ko pelu Theodor Adorno, The Dialectic of Enlightenment (1947). O sese opo pataki ni Frankfurt School.[1]
Itokasi