"Kano Pillars" túndarí síbí yìí. Fún the basketball club, ẹ wo
Kano Pillars BC.
Kano Pillars F. C. jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-agbáṣiṣẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Kano ni Nigeria. Wọ́n máa ń kópa nínú ìdíje kékeré nínú ìdíje líìgì àgbábuta bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí Nigeria. Wọ́n dá ẹgbẹ́ Kano Pillars yìí sílẹ̀ lọ́dún 1990, ọdún tí bọ́ọ̀lù agbáṣiṣẹ́ bẹ̀rẹ̀ ní Nigeria, ẹgbẹ́ yìí jẹ́ àdàpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù abẹ́lé mẹ́ta ní Ìpínlẹ̀ Kano.
Àwọn Ìtọ́kasí