Henry Dunant
Jean Henri Dunant (May 8, 1828 – October 30, 1910), aka Henry Dunant, je ara Swiss onisowo ati alakitiyan awujo. Nigba irinajo owo to se ni 1859 o ri esi Ija Solferino ni Italy loni. O ko gbogbo iriri re sile ninu iwe to pe ni A Memory of Solferino eyi lo fa idasile Igbimo Kariaye Agbelebu Pupa (ICRC) ni 1863. Iwe Ipinnu Geneva odun 1864 duro lori adaro Dunant. Ni odun 1901 o gba Ebun Nobel Alafia akoko pelu Frédéric Passy. Itokasi
Information related to Henry Dunant |