Friedrich Engels

Friedrich Engels
Friedrich Engels
OrúkọFriedrich Engels
Ìbí28 November 1820
Barmen, Prussia
Aláìsí5 August 1895(1895-08-05) (ọmọ ọdún 74)
London, England
Ìgbà19th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Marxism
Ìjẹlógún ganganPolitical philosophy, Politics, Economics, class struggle, capitalism
Àròwá pàtàkìCo-founder of Marxism (with Karl Marx), alienation and exploitation of the worker, historical materialism
Ìtọwọ́bọ̀wé

Friedrich Engels (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈɛŋəls]; 28 November 1820 – 5 August 1895) je omo Jemani onimosayensi awujo, oludako, oludero oloselu, onimo oye, ati baba ero komunisti, pelu Karl Marx. Awon mejeji ni won ko Manifesto Komunisti ni 1848. Engels si tun solotu iwe keji ati iketa Das Kapital leyin iku Marx.


Itokasi