Empress Njamah |
---|
Ọjọ́ìbí | November 16 [1] |
---|
Iṣẹ́ | Actor |
---|
Empress Njamah jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2][3] Ní ọdún 2012, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ Best supporting actress láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Award.
Ìgbésí ayé rẹ̀
Àwọn òbí Njamah jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Cameroon. Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Olabisi Onabanjo University nínú ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì. Ó jẹ́ olólùfẹ́ fún olórin, Timaya tẹ́lẹ̀[4][5]. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 1995. Ó dá ẹgbẹ́ House of Empress kalẹ̀ láti má ṣe ìtọ́jú fún àwọn ọmọdé.[6][7]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
Ọdún
|
Àkọ́lé eré
|
Ipa tí ó kó
|
2000
|
Girls Hostel
|
Tunica
|
2004
|
Missing Angel
|
|
2006
|
Liberian Girl
|
|
Àwọn ìtọ́kàsi