Ìjọ Deeper Christian Life Ministry tí a tún mò si ìjo Deeper Life jé ìjo onihinrere tí o olú rè kalè sí Gbàgádà, ìpínlè eko ní Nàìjirià[1]. Láti ọwọ́ Pastor Folorunso William Kumuyi(eni tí o jé adari ijo náà) dá ijo náà sílẹ̀ ní ọdún 1973 [2], ìjo náà bere bí egbe ikeko bibeli pèlú àwon akeko meedogun ti Yunifásitì ìlú èkó[3] ní odún 1973, láti igbana, ijona ti gboro kakiri agbaye.