Bioclinix Medical Diagnostics CentreBioclinix Medical Diagnostics Centre jẹ́ Ilé-àyẹ̀wò-ara aládàáni tí ó ní àṣẹ àti oǹtẹ̀ ìjọba Ìpínlè Èkó láti ọwọ́ àjọ tí ó ń m'ójú tó nǹkan ètò-ìlera, Health Facility Monitoring and Accreditation Agency (HEFAMAA) [1][2] láti máa ṣe àyẹ̀wò ara fún oríṣiríṣi àìsàn àti àìlera lọ́lọ́kan-ò-jọ̀kan.[3]. Ilé-àyẹ̀wò-ara aládàáni yìí wà ní ìlú Badagry, Ìpínlẹ̀ Èkó, l'órílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀ ìgbà ní ilé-iṣẹ́ náà máa ń ṣe àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ àti ẹ̀dínwó fún àwọn olùgbé Badagry àti àgbègbè, rẹ̀ kí wọ́n ba lè ní aǹfàní láti ṣe ìtọ́jú tó péye fún àgọ́-ara wọn[4]. Àwọn ẹ̀ka àyẹ̀wò-araIlé-àyẹ̀wò-ara yìí ní ẹ̀ka àyẹ̀wò-ara lóríṣiríṣị tí wọ́n ń ṣe fún àwọn ará ìlú. Lára wọn ni:
Àwọn ìtọ́kasí
Information related to Bioclinix Medical Diagnostics Centre |