Babcock University jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládẹ́tẹ̀ nípa ẹ̀sìn Kristi tí ó jẹ́ ẹni t’ọmọ àti ọmọbìnrin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí Seventh-day Adventist Church ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni ó nísẹ́, tí wọ́n sì ń darí. Ilé-ẹ̀kọ́ gíga yìí wà ní Ìlíshàn-Remo, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà, tó sì wà nínú ààrin Ibàdàn àti Èkó.
Ní ọdún 2017, ilé-ẹ̀kọ́ náà ní àkọ́kọ́ ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tó kà á tan láti Ben Carson School of Medicine.
Ó jẹ́ apá kan nínú ètò ẹ̀kọ́ Seventh-day Adventist Church, èyí tí í ṣe ètò ẹ̀kọ́ Kristẹni kejì tó tóbi jù lọ ní àgbáyé.[2][3][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 Office of Archives, Statistics, and Research. "Babcock University". Adventist Yearbook. Retrieved 1 January 2018.
- ↑ Kido, Elissa (2010-11-15). "For real education reform, take a cue from the Adventists". The Christian Science Monitor. Retrieved 2020-03-02.
- ↑ "Seventh Day Adventist". Archived from the original on 23 March 2015. Retrieved 2016-03-31.
- ↑ "Department of Education, Seventh-day Adventist Church". Archived from the original on 17 October 2017. Retrieved 2010-06-18.
- ↑ Rogers, Wendi; Kellner, Mark (1 April 2003). "World Church: A Closer Look at Higher Education". Adventist News Network. Retrieved 2020-03-02.