Amartya Kumar Sen, CH (Bẹ̀ngálì: অমর্ত্য কুমার সেন, Ômorto Kumar Shen; ojoibi 3 November 1933) je ara India aseoro-okowo to gba ni 1998 Ebun Nobel ninu awon Sayensi Oro-Okowo fun ipa re si oro-okowo itoju awujo ati iro ayanmu awujo, ati fun ijologun re si awon isoro awon talaka awujo.[1] Sen gbajumo fun ise re lori awo ohu ti o unfa iyan, to fa idagbasoke ojutu amulo wa lati dina tabi kekuru awon ipa aito onje lawujo. Lowolowo ohun ni Ojogbon Yunifasiti aga Thomas W. Lamont ati Ojogbon Oro-Okowo ati Imoye ni Harvard University. O je elegbe agba ni Harvard Society of Fellows ati elegbe Trinity College, Cambridge, nibi to ti sise teletele bi Oga lati 1998 di 2004.[2][3] Ohun olukoni ara Asia ati India akoko to je olori koleji Oxbridge.
Itokasi
|
---|
1969–1975 | |
---|
1976–2000 | |
---|
2001–dòní | |
---|
|