Alhaji Muhammed Rájí Àlàbí Owónikókó Jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà,olórin Àpàlà. Wọ́n bí Rájí ní ìlú Òró ní ijoba ibile Irepodun ìpínlẹ̀ Kwárà.[1] [2] [3]
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.