Ogbomosho South |
---|
|
Country | Nigeria |
---|
State | Oyo State |
---|
Government |
---|
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Oyeniyi Timothy Oyedokun (PDP)
Traditional ruler Onijeru of ijeruland |
---|
Time zone | UTC+1 (WAT) |
---|
Ogbomosho South jẹ́ agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ́-èdè Nàìjíríà. Olú ìlú Gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ wà ní agbègbè Arówómọlé ní ìlú Ògbómọ̀ṣọ́. Ó fẹ̀ ní ìwọ̀n 88km², ní ọdún 2006 wọ́n ka iye ènìyàn tí ó wà níbè sí 185,815.
Nọ́mbà ìfi lẹ́tà jíṣẹ́ sí ìlú náà ni 210.[1]
Ìjọba Ológun dá agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ sílẹ̀ ní ọdún 1991 láti ara ìjọba ìbílẹ̀ Ògbómọ̀ṣọ́ tẹ́lẹ̀. Àwọn ìlú tí ó yí ìjọba ìbílẹ̀ gúúsù Ògbómọ̀ṣọ́ ni Idi- igba, Gaa- Lagbedu, Kajola, Kowe, Oke- Ola, Adeoye, Onidewure, Molete, Arowomole, Sanuaje, Obandi, Ijeru, Ayegun, and Oke Alapata.[2]
Àwọn Ibi tó gbajúmọ̀
State Hospital Complex – Sodiq Sekendegbe Street, Arowomole
Secretariat Complex – Arowomole
The Apostolic Church, Alapata Assembly[3]
National Museum, Arowomole
Nigerian Baptist Theological Seminary
Beulah Baptist Centre
State Library – Arowomole
Federal Housing Estate – Ibapon Road
Industrial Estate – Osogbo Road
Idi-Oro Baptist Church
Akande Market – Caretaker
DAD Foundation Sports Arena, Idi-Oro
Federal Road Safety Corps – Oluwatedo
Maryland Catholic High School
Methodist Cathedral – Arowomole
Berean Independent Baptist Church – Kajola
St Anne Catholic Church – Arinkinkin
St Ferdinand Catholic Church
Onpetu of Ijeru Palace
Government Technical college, Kajola
Baptist Secondary Grammar School, Ahoyaya.
The Apostolic Primary School II
Abede Primary School[2]
The Apostolic Model School
Aarada Market – Osogbo Road
Ayegun Primary School II
A.U.D Primary School, Awoye Street.
Kajola Primary School
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on November 26, 2012. Retrieved 2009-10-20.
- ↑ 2.0 2.1 "OGBOMOSO SOUTH LOCAL GOVERNMENT – Oyo State Government" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-05.
- ↑ "The Apostolic Church Nigeria, Alapata Assembly, Ogbomoso. 🇳🇬 - WorldPlaces". nigeria.worldplaces.me (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-05.